Akínṣílé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínṣílé
The warrior has commissioned/open the house.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-ṣí-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave oneṣí - open
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO