Akéréburú
Sísọ síta
Ìtumọọ Akéréburú
One tough enough as a young child.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Akérékorò, Akéréle
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-kéré-burú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one who (is)kéré - young, small, immature
burú - be tough, be wicked
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL