Akọ́ládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Akọ́ládé

One who brings success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-kó-ọlá-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
kó - gather
ọlá - success, nobility, wealth
dé - arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kọ́lá

Kọ́ládé