Akọ̀yà

Sísọ síta



Ìtumọọ Akọ̀yà

One who rejects suffering.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-kọ-ìyà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
kọ - to reject
ìyà - suffering, punishment


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kọ̀yà