Akíntúlà

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíntúlà

Valor has survived again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-tú-là



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
- is worth (tó)
- to survive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Akíntúnlà