Akíntómọwọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíntómọwọ́
The warrior is worthy of knowing one's hand.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-tó-mọ-ọwọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onetó - enough for, suffice for
mọ - know, recognize
ọwọ́ - (a helping) hand
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO