Akínpẹtìdé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínpẹtìdé
The warrior has stopped the controversy. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-pa...dé-ẹtì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onepa...dé - to shut firmly
ẹtì - impossibility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO