Akínnúsì

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínnúsì

Valor has repute.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-ní-ùsì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
- have
ùsì - fame, reputation, renown


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI