Akínmúlésanmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínmúlésanmí
The warrior has made the house befit me.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-mú-ilé-san-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valormú - make
ilé - home, house
san - be good, be improved, benefit, befit, pay
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE