Akínmáyọ̀kún
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínmáyọ̀kún
The warrior made joy full.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-mú-ayọ̀-kún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onemú - to use; to hold (onto); to make
ayọ̀ - joy
kún - in addition to, fulfillment
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO