Akínjọbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínjọbí

The warrior has joined in the birth (of this child).



Àwọn àlàyé mìíràn

Descendants of an Ọọ̀ni of Ifẹ̀ bear this name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-jọ-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
jọ - together, in collaboration
- to give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Akínjọbí (1820-1834)

  • the last Olowu of Owu before the destruction of the Owu homeland



Irúurú

Akíjọbí