Akíngùnsọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíngùnsọ́lá

The warrior has ascended into honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-gùn-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
gùn - climb, mount, to ascend to
- into
ọlá - wealth/nobility/success/honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Gùnsọ́lá