Akínfóyèkù
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínfóyèkù
The warrior does not lack more titles (as an addition to his wealth).
Àwọn àlàyé mìíràn
See Olówòfóyèkù
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-ò-fẹ́...kù-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave oneò - did not
fẹ́...kù - to lack
oyè - honour, respect, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO