Akíndìjí

Sísọ síta



Ìtumọọ Akíndìjí

The warrior has become a powerful wind.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-di-ìjí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
di - become
ìjí - storm


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dìjí