Akíndóyètẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíndóyètẹ́
Bravery did not allow our honor to be disgraced. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-ò-dí-oyè-tẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave oneò - is not, does not
dí - to allow (jí, jẹ́)
oyè - honor, chieftaincy ttle
tẹ́ - be disgraced
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO