Akíndólírẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíndólírẹ̀
The warrior has established his household.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-dó-ulí-rẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave onedó - started, establish, founded
ulí - house, home (ilé)
rẹ̀ - his, hers
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO