Akínbínúadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Akínbínúadé

The warrior is not upset at the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-ò-bínú-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
ò - did not
bínú - be angry
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Akínbínú