Akínṣadérẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Akínṣadérẹ̀
The warrior has made his crown.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-ṣe-adé-rẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the brave oneṣe - make, create
adé - crown, royalty
rẹ̀ - his, hers
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO