Akéwúyanjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Akéwúyanjú

One who succeeded in the studies of the Quran.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-kéwú-yanjú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
kéwú - to recite the Quran
yanjú - to complete, to finish, to succeed


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Akéúyanjú