Akẹ́nmúléró

Sísọ síta



Ìtumọọ Akẹ́nmúléró

A variant of Akínmúléró, bravery upholds the house.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

akin-mú...ró-ulé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

akin - valor, bravery, the brave one
mú...ró - uphold
ulé - house, home (ilé)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILAJE
OWO



Irúurú

Akínmúléró