Ajímájàṣán
Sísọ síta
Ìtumọọ Ajímájàṣán
One who never eats bland (food) in the morning.
Àwọn àlàyé mìíràn
A cognomen, oríkì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-jí-má-jẹ-àṣán
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whojí - wake up, arise
má - do not
jẹ - eat
àṣán - bland food
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL