Ajíbọ́ládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajíbọ́ládé

One who wakes up to, and arrives with, success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-jí-bá-ọlá-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
jí - wake up
bá - together with
ọlá - success, notability, nobility, wealth
dé - arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ajíbọ́lá

Bọ́lá

Bọ́ládé