Ajéwámirí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajéwámirí

The spirit of industry/enterprise has sought (and found) me.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Olúwámirí, Iréwámirí, Ọmọ́wámirí, Ògúnwámirí, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ajé-wá-mi-rí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ajé - business, enterprise, wealth, Ajé, goddess of wealth and money
- to find
mi - me, my
- see, find


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Wámirí

Olúwámirí

Iréwámirí

Ọmọ́wámirí

Ògúnwámirí

Adéwámirí

Ọláwámirí

Ọ̀ṣúnwámirí