Ajéfowókẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ajéfowókẹ́
The spirit of business pampered (him/her) with money.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ajé-fi-owó-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ajé - business, enterprise, wealth, Ajé, goddess of wealth and moneyfi - used
owó - money, cowries
kẹ́ - cherish, care for, pet
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL