Ajófóyìnbó

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajófóyìnbó

A nickname meaning, The one who dances for the white man/foreigner.



Àwọn àlàyé mìíràn

Also a nickname for a type of Egúngún.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-jó-fún-òyìnbó



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - we, one who
- dance
fún - give to, gift to; for
òyìnbó - white man, European


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI