Ajíshekọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ajíshekọ́lá
One who wakes up to add more to his/her prestige.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Aríṣekọ́lá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-jí-ṣe-kún-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someonejí - wake up
ṣe - make, create
kún - fill, add to
ọlá - honour, wealth, success, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OSUN