Ajíṣegbẹ́dẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajíṣegbẹ́dẹ́

The one who wakes up and is deeply comfortable (verification needed).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-jí-ṣe-gbẹ́dẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
- wake up
ṣe - make, create
gbẹ́dẹ́ - to be deeply comfortable or pleasured


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Jíṣegbẹ́dẹ́