Aiyélábẹ́gàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Aiyélábẹ́gàn

We meet detract(ors) in the world.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

aiyé-ni-a-bá-ẹ̀gàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

aiyé - life, world, earth
ni - is (where)
a - we
bá - meet, find
ẹ̀gàn - mockery


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ayélabẹ́gàn