Agírí

Sísọ síta



Ìtumọọ Agírí

One who goes about his business in haste.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a short form of Ajíṣegírí.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-(jí-ṣe)-gírí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
jí - wake up, arise
ṣe - make
gírí - haste


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL