Agbanilolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Agbanilolúwa

The Lord is a saviour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-gba-ẹni-ni-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
gbà - save
ẹni - person
ni - is
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN