Agbáraolúwakìbatì

Sísọ síta



Ìtumọọ Agbáraolúwakìbatì

God's power never fails.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

agbára-olúwa-kìí-bàá-tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

agbára - power
olúwa - lord, God
kìí - does not
bàá - touch (it)
tì - fail


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Agbáraolúwakìíbàátì