Afúnbiowó
Sísọ síta
Ìtumọọ Afúnbiowó
The one who is as clean/white as cowries.
Àwọn àlàyé mìíràn
A cognomen/oríkì
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-fún-bi-owó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whofún - to be white; to be clean (fín)
bi - like
owó - money, cowries
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Oba Ọlọ́finladé Afúnbiowó (Adéṣidà I)
Deji of Akure (1897-1957) Oba Afúnbiowó II
Deji of Akure (2010-2013)