Sísọ síta
One who walks with honor.
a-fi-ọlá-rìn
Ó pọ̀ ní: GENERAL
Fọlárìn
Fọlá
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.