Afọlámí

Sísọ síta



Ìtumọọ Afọlámí

He breathes wealth/honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-fi-ọlá-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
fi - use
ọlá - wealth, success, honour
mí - breathe


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fọlámí

Fọlá