Afọdúnrìnbí
Sísọ síta
Ìtumọọ Afọdúnrìnbí
One who came during a festive season.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-fi-ọdún-rìn-bí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whofi - use
ọdún - year, festivities, season
rìn - walk
bí - give birth to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS