Afẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Afẹ́
1. Fashion. Fashionable. 2. (What) we want.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a common root in many names in Yorùbá, like Ẹniafẹ́, Kọ́mọláfẹ, etc.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
afẹ́, a-fẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
afẹ́ - fashiona - one who
fẹ́ - love, want, desire
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Afẹ́ Babalọlá: Nigerian lawyer.