Afìdípọ̀tẹ̀mọ́lẹ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Afìdípọ̀tẹ̀mọ́lẹ̀
One who is capable of using reasoning to stop rebellion.
Àwọn àlàyé mìíràn
A nickname used as a praise name for many kings, perhaps most prominently, former Àwùjalẹ̀ (king) of Ijebuland, Oba Afidìpọ̀tẹ̀mọlẹ̀ Adémuyewo
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-fi-ìdí-pa-ọ̀tẹ̀-mọ́-ilẹ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - one whofi - put
ìdí - bottom, butt, reason, source, foundation
pa - kill, drown, quench
ọ̀tẹ̀ - rebellion, intrigue, betrayal
mọ́ - to
ilẹ̀ - ground
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU