Adúródọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Adúródọlá

1. We waited for success. 2. One who waits for success.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dúró-de-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who, we
dúró...dè - stand with, wait for
ọlá - success, wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dúródọlá

Dọlá