Adúmáradán

Sísọ síta



Ìtumọọ Adúmáradán

One with a dark and shiny skin. One who shines through his/her dark complexion.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dú(dú)-mú-ara-dán



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
dúdú - dark
mú - make
ara - body, skin
dán - shine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adúmáadán