Adú

Sísọ síta



Ìtumọọ Adú

The dark-complexioned one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-dú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who is
dú - dark-skinned, dúdú


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Joseph Abíọ́dún Babátúndé Adú (1933-2016)

  • veteran actor.



Ibi tí a ti lè kà síi



Irúurú

Adúmáradán