Adùnbárìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Adùnbárìn
One sweet to walk with.
Àwọn àlàyé mìíràn
One with a good and pleasant attitude. When someone is called "Adùn ń bá rìn má tòṣì, it means that you can't go poor/destitute walking with them."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
a-dùn-bá-rìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
a - someonedùn - sweet
bá - together with
rìn - walk
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL