Adétówùnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Adétówùnmi

The crown that I desire.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-tí-ó-wùn-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
tí - that
- it
wù/wùn - attract
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adétówùmi

Tówùmí

Wùmí

Wùnmí