Adémúlẹ̀gún
Sísọ síta
Ìtumọọ Adémúlẹ̀gún
The crown has made the town proper.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-mú-ilẹ̀-gún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royalty, nobilitymú - pick, carry, hold
ilẹ̀ - ground
gún - be proper, be appropriate, be just
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI