Adéfọlárìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéfọlárìn
The crown uses wealth to walk.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-fi-ọlá-rìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltyfi - use
ọlá - wealth, royalty
rìn - walk
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Adéfọlárìn Dúrósinmí( Footballer) Prof Málọmọ́ Adéfọlárìn O. (Lecturer) Adéfọlárìn Ogunsanya(Investement Professional)