Adéyanjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéyanjú

The crown is complete.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-yanju



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown
yanjú - complete, finish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Adé

Yanjú

Déyanjú