Adéyọjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéyọjú

Royalty showed up.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-yọ-ojú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
yọ - show
ojú - face


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OSUN



Irúurú

Déyọjú