Adéyẹ́misí

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéyẹ́misí

The Crown honors me



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

Adé-yẹ́-mi-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

Adé - crown, royalty
yẹ́...sí - honor, celebrate
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Yẹ́misí