Adéwọrọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéwọrọ̀

The crown has entered into riches.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-wọ-ọrọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
wọ - enter
ọrọ̀ - wealth, riches


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA