Adétóyọ̀sí

Sísọ síta



Ìtumọọ Adétóyọ̀sí

The crown is worth rejoicing unto.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-tó-yọ̀-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
- sufficient for
yọ̀ - rejoice
- to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Détóyọ̀sí

Tóyọ̀sí