Adétówún

Sísọ síta



Ìtumọọ Adétówún

Royalty is worth celebrating.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Adétóún



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-tó-wún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
tó - suffice for
wún/hún - rejoice over, celebrate


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Adétóún